...

1 views

Oyo- Anthem
Ilu OYO, mo fe o denu
N o sin o, tokan Tara
A ji sebi OYO laari,
Oyo- o gbodo sebi enikan

Ma fo wo mi, Pele imo
Ogbon ori mi, pelu ero
Gbogo Ilu tabi mi ga

Ilu OYO, ilu olola
Ilu OYO, ilu oloba
Ilu ologbon, ilu omoran

Ilu t'Olorun se ni Pataki
Ilu t'Olorun yonu si

Omode OYO, e mura giri
Agba OYO, emura kole
Ile Wa o letu loju

Nile l'oko, OYO o s'ole
Titepa mose la fi nyangan
Ise owo awa, L'awa gbojule

Ninu Oba, OYO l'olori,
Alaafin lagba Oba
Ilu OYO gbayi, o si me to

Esin iwaju, ko gbodo reyin
Ko OYO sowopo, ka le lo siwaju

Waju ni
E e waju ni,
Ilu OYO koni reyin
Waju, la o ma lo

English Translation
Oyo- a town, I love wholeheartedly
I shall uplift...